1
Jeremiah 42:6
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
BMYO
Ìbá à ṣe rere, ìbá à ṣe búburú, àwa yóò gbọ́rọ̀ sí OLúWA Ọlọ́run wa, èyí tí àwa ń rán ọ sí, kí ó ba à lè dára fún wa. Nítorí pé àwa yóò gbọ́rọ̀ sí OLúWA Ọlọ́run wa.”
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Jeremiah 42:6
2
Jeremiah 42:11-12
Ẹ má ṣe bẹ̀rù ọba Babeli tí ẹ̀yin ń bẹ̀rù, báyìí ẹ má ṣe bẹ̀rù rẹ̀ ni OLúWA wí; nítorí tí èmi wà pẹ̀lú yín láti pa yín mọ́ àti láti gbà yín ní ọwọ́ rẹ̀. Èmi yóò fi àánú hàn sí i yín, kí ó lè ṣàánú fún un yín, kí ó sì mú un yín padà sí ilẹ̀ yín.’
Ṣàwárí Jeremiah 42:11-12
3
Jeremiah 42:3
Gbàdúrà pé kí OLúWA Ọlọ́run rẹ sọ ibi tí àwa yóò lọ fún wa àti ohun tí àwa yóò ṣe.”
Ṣàwárí Jeremiah 42:3