1
Jobu 28:28
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Àti fún ènìyàn ni ó wí pé, “Kíyèsi i, ẹ̀rù Olúwa èyí ni ọgbọ́n, àti láti jáde kúrò nínú ìwà búburú èyí ni òye.”
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Jobu 28:28
2
Jobu 28:12-13
Ṣùgbọ́n níbo ni á ó gbé wá ọgbọ́n rí, níbo sì ni òye ń gbe? Ènìyàn kò mọ iye rẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni a kò le è rí i ní ilẹ̀ àwọn alààyè.
Ṣàwárí Jobu 28:12-13
3
Jobu 28:20-21
Níbo ha ni ọgbọ́n ti jáde wá? Tàbí níbo ni òye ń gbé? A rí i pé, ó fi ara sinko kúrò ní ojú àwọn alààyè gbogbo, ó sì fi ara sin fún ẹyẹ ojú ọ̀run.
Ṣàwárí Jobu 28:20-21
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò