1
Joṣua 3:5
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Joṣua sì sọ fún àwọn ènìyàn pé, “Ẹ ya ara yín sí mímọ́, nítorí ní ọ̀la, OLúWA yóò ṣe ohun ìyanu ní àárín yín.”
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Joṣua 3:5
2
Joṣua 3:7
OLúWA sì sọ fún Joṣua pé, “Òní yìí ni Èmi yóò bẹ̀rẹ̀ sí í gbé ọ ga ní ojú u gbogbo àwọn ará Israẹli, kí wọn lè mọ̀ pé Èmi wà pẹ̀lú rẹ gẹ́gẹ́ bí mo ṣe wà pẹ̀lú Mose.
Ṣàwárí Joṣua 3:7
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò