1
Òwe 27:17
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Bí irin tí ń pọ́n irin mú bẹ́ẹ̀ ni ènìyàn kan ń pọ́n ẹlòmíràn mú.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Òwe 27:17
2
Òwe 27:1
Má ṣe yangàn nítorí ọ̀la nítorí o kò mọ ohun tí ọjọ́ kan le è mú wáyé.
Ṣàwárí Òwe 27:1
3
Òwe 27:6
Òtítọ́ ni ọgbẹ́ ọ̀rẹ́, ṣùgbọ́n ìfẹnukonu ọ̀tá ni ẹ̀tàn.
Ṣàwárí Òwe 27:6
4
Òwe 27:19
Bí omi tí ń ṣe àfihàn ojú, nígbà tí a bá wò ó bẹ́ẹ̀ ni ọkàn ènìyàn ń ṣe àfihàn ènìyàn.
Ṣàwárí Òwe 27:19
5
Òwe 27:2
Jẹ́ kí ẹlòmíràn yìn ọ́ dípò ẹnu ara rẹ àní àlejò, kí ó má sì ṣe ètè ìwọ fúnrarẹ̀.
Ṣàwárí Òwe 27:2
6
Òwe 27:5
Ìbániwí gbangba sàn ju ìfẹ́ ìkọ̀kọ̀ lọ.
Ṣàwárí Òwe 27:5
7
Òwe 27:15
Àyà tí ó máa ń jà dàbí ọ̀wààrà òjò ní ọjọ́ tí òjò ń rọ̀
Ṣàwárí Òwe 27:15
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò