Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ Òwe 5

1

Òwe 5:21

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Nítorí ọ̀nà ènìyàn kò fi ara sin rárá fún OLúWA Ó sì ń gbé gbogbo ọ̀nà rẹ̀ yẹ̀ wò.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Òwe 5:21

2

Òwe 5:15

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Mu omi láti inú kànga tìrẹ, omi tí ń sàn láti inú kànga rẹ.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Òwe 5:15

3

Òwe 5:22

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Ìwà búburú ènìyàn búburú ni yóò mú kó bọ́ sínú okùn; okùn ẹ̀ṣẹ̀ ara rẹ̀ yóò sì dìímú.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Òwe 5:22

4

Òwe 5:3-4

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Nítorí ètè àwọn àjèjì obìnrin a máa sun bi oyin, ọ̀rọ̀ rẹ̀ sì kúnná ju òróró lọ. Ṣùgbọ́n ní ìgbẹ̀yìn gbẹ́yín, ó korò ju òróǹró lọ, ó mú bí idà olójú méjì.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Òwe 5:3-4

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
Yorùbá

©2026 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest