1
Saamu 104:34
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Jẹ́ kí ẹ̀kọ́ mi kí ó tẹ́ ọ lọ́rùn bí mo ti ń yọ̀ nínú OLúWA.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 104:34
2
Saamu 104:33
Ní gbogbo ayé mi ní n ó kọrin sí OLúWA: èmi ó kọrin ìyìn sí OLúWA níwọ̀n ìgbà tí mo wà láààyè.
Ṣàwárí Saamu 104:33
3
Saamu 104:1
Yin OLúWA, ìwọ ọkàn mi. OLúWA Ọlọ́run mi, ìwọ tóbi jọjọ; ọlá àti ọláńlá ni ìwọ wọ̀ ní aṣọ.
Ṣàwárí Saamu 104:1
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò