1
Saamu 111:10
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
BMYO
Ìbẹ̀rù OLúWA ni ìpilẹ̀ṣẹ̀ ọgbọ́n: òye dáradára ni yóò máa ṣe òfin rẹ̀, ìyìn rẹ̀ dúró láé.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 111:10
2
Saamu 111:1
Ẹ máa yin OLúWA. Èmi yóò máa yin OLúWA pẹ̀lú gbogbo ọkàn mi, ní àwùjọ àwọn olóòtítọ́, àti ní ìjọ ènìyàn.
Ṣàwárí Saamu 111:1
3
Saamu 111:2
Iṣẹ́ OLúWA tóbi, àwọn tí ó ní inú dídùn, ń ṣe àṣàrò nínú rẹ̀.
Ṣàwárí Saamu 111:2