1
Saamu 112:7
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Òun kì yóò béèrè ìyìn búburú: ọkàn rẹ̀ ti dúró, ó ní ìgbẹ́kẹ̀lé nínú OLúWA.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 112:7
2
Saamu 112:1-2
Ẹ fi ìyìn fún OLúWA. Ìbùkún ni fún ọkùnrin náà tí ó bẹ̀rù Ọlọ́run, tí ó ní inú dídùn ńlá sí àwọn òfin rẹ̀. Irú-ọmọ rẹ̀ yóò jẹ́ alágbára ní ayé: ìran àwọn olóòtítọ́ ni a ó bùkún fún.
Ṣàwárí Saamu 112:1-2
3
Saamu 112:8
Ó ti mú ọkàn rẹ̀ gbilẹ̀, ẹ̀rù kí yóò bà á, títí yóò fi rí ìfẹ́ ọkàn rẹ̀ lórí àwọn ọ̀tá rẹ̀.
Ṣàwárí Saamu 112:8
4
Saamu 112:4
Fún olóòótọ́ ni ìmọ́lẹ̀ yóò tàn fún ní òkùnkùn: olóore-ọ̀fẹ́ àti aláàánú àti òdodo.
Ṣàwárí Saamu 112:4
5
Saamu 112:5
Ènìyàn rere fi ojúrere hàn, a sì wínni; ìmòye ni yóò máa fi la ọ̀nà iṣẹ́ rẹ̀.
Ṣàwárí Saamu 112:5
6
Saamu 112:6
Dájúdájú a kì yóò le yí ní ipò padà láéláé: olódodo ni a ó máa ṣe ìrántí rẹ láéláé.
Ṣàwárí Saamu 112:6
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò