1
Saamu 113:3
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
BMYO
Láti ìlà-oòrùn títí dé ìwọ̀ rẹ̀ orúkọ OLúWA ni kí a máa yìn.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 113:3
2
Saamu 113:9
Ó mú àgàn obìnrin gbé inú ilé, àti láti jẹ́ aláyọ̀ ìyá fún àwọn ọmọ rẹ̀. Ẹ yin OLúWA.
Ṣàwárí Saamu 113:9
3
Saamu 113:7
Ó gbé òtòṣì dìde láti inú erùpẹ̀, àti pé ó gbé aláìní sókè láti inú ààtàn wá.
Ṣàwárí Saamu 113:7