1
Saamu 121:1-2
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
BMYO
Èmi yóò gbé ojú mi sórí òkè wọ̀n-ọn-nì— níbo ni ìrànlọ́wọ́ mi yóò ti wá? Ìrànlọ́wọ́ mi tí ọwọ́ OLúWA wá, ẹni tí ó dá ọ̀run òun ayé.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 121:1-2
2
Saamu 121:7-8
OLúWA yóò pa ọ́ mọ́ kúrò nínú ibi gbogbo yóò pa ọkàn rẹ mọ́ OLúWA yóò pa àlọ àti ààbọ̀ rẹ mọ́ láti ìgbà yìí lọ àti títí láéláé.
Ṣàwárí Saamu 121:7-8
3
Saamu 121:3
Òun kì yóò jẹ́ kí ẹsẹ̀ rẹ kí ó yẹ̀; ẹni tí ó pa ọ́ mọ́ kì í tòògbé.
Ṣàwárí Saamu 121:3