1
Saamu 150:6
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Jẹ́ kí gbogbo ohun tí ó ní ẹ̀mí yin OLúWA. Ẹ fi ìyìn fún OLúWA.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 150:6
2
Saamu 150:1
Ẹ fi ìyìn fún OLúWA. Ẹ fi ìyìn fún Ọlọ́run ní ibi mímọ́ rẹ̀ Ẹ yìn ín nínú agbára ọ̀run rẹ̀.
Ṣàwárí Saamu 150:1
3
Saamu 150:2
Ẹ yìn ín fún iṣẹ́ agbára rẹ̀. Ẹ yìn ín fún títóbi rẹ̀ tí ó tayọ̀.
Ṣàwárí Saamu 150:2
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò