1
Saamu 18:2
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
OLúWA ni àpáta àti odi mi, àti olùgbàlà mi; Ọlọ́run mi ni àpáta mi, ẹni tí mo fi ṣe ibi ìsádi mi. Òun ni àpáta ààbò àti ìwo ìgbàlà mi àti ibi ìsádi mi.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 18:2
2
Saamu 18:30
Bí ó ṣe ti Ọlọ́run mi, ọ̀nà rẹ̀ pé, a ti rídìí ọ̀rọ̀ OLúWA òun ni àpáta ààbò fún gbogbo àwọn tí ó fi ṣe ààbò.
Ṣàwárí Saamu 18:30
3
Saamu 18:3
Mo ké pe OLúWA, ẹni tí ìyìn yẹ fún, a ó sì gbà mí lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá à mi.
Ṣàwárí Saamu 18:3
4
Saamu 18:6
Nínú ìpọ́njú mo ké pe OLúWA; Mo sọkún sí OLúWA mi fún ìrànlọ́wọ́. Láti inú tẹmpili rẹ̀, ó gbọ́ igbe mi; ẹkún mi wá sí iwájú rẹ̀, sí inú etí rẹ̀.
Ṣàwárí Saamu 18:6
5
Saamu 18:28
Ìwọ, OLúWA, jẹ́ kí fìtílà mi kí ó máa tàn; Ọlọ́run mi, yí òkùnkùn mi padà sí ìmọ́lẹ̀.
Ṣàwárí Saamu 18:28
6
Saamu 18:32
Ọlọ́run ni ẹni tí ó fi agbára dì mí ní àmùrè ó sì mú ọ̀nà mi pé.
Ṣàwárí Saamu 18:32
7
Saamu 18:46
OLúWA wà láààyè! Olùbùkún ni àpáta mi! Gbígbéga ní Ọlọ́run Olùgbàlà mi.
Ṣàwárí Saamu 18:46
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò