1
Saamu 24:1
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ti OLúWA ni ilẹ̀, àti ẹ̀kún rẹ̀, ayé àti àwọn tí ó tẹ̀dó sínú rẹ̀
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 24:1
2
Saamu 24:10
Ta ni Ọba ògo náà? OLúWA àwọn ọmọ-ogun Òun ni Ọba ògo náà. Sela.
Ṣàwárí Saamu 24:10
3
Saamu 24:3-4
Ta ni yóò gun orí òkè OLúWA lọ? Ta ni yóò dúró ní ibi mímọ́ rẹ̀? Ẹni tí ó ní ọwọ́ mímọ́ àti àyà funfun, ẹni tí kò gbé ọkàn rẹ̀ sókè sí asán tí kò sì búra èké.
Ṣàwárí Saamu 24:3-4
4
Saamu 24:8
Ta ni ọba ògo náà? OLúWA tí ó lágbára tí ó sì le, OLúWA gan an, tí ó lágbára ní ogun.
Ṣàwárí Saamu 24:8
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò