1
Saamu 3:3
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ṣùgbọ́n ìwọ ni asà yí mi ká, OLúWA; ìwọ fi ògo fún mi, ìwọ sì gbé orí mi sókè.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 3:3
2
Saamu 3:4-5
OLúWA ni mo kígbe sókè sí, ó sì dá mi lóhùn láti orí òkè mímọ́ rẹ̀ wá. Sela. Èmi dùbúlẹ̀, mo sì sùn; mo sì tún padà jí, nítorí OLúWA ni ó ń gbé mi ró.
Ṣàwárí Saamu 3:4-5
3
Saamu 3:8
Láti ọ̀dọ̀ OLúWA ni ìgbàlà ti wá. Kí ìbùkún rẹ wà lórí àwọn ènìyàn rẹ. Sela.
Ṣàwárí Saamu 3:8
4
Saamu 3:6
Èmi kì yóò bẹ̀rù ẹgbẹgbẹ̀rún ènìyàn tí wọ́n rọ̀gbà yí mi ká.
Ṣàwárí Saamu 3:6
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò