1
Saamu 38:22
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Yára láti ràn mí lọ́wọ́, OLúWA, Olùgbàlà mi.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 38:22
2
Saamu 38:21
Má ṣe kọ̀ mí sílẹ̀, ìwọ OLúWA! Ọlọ́run mi, Má ṣe jìnnà sí mi.
Ṣàwárí Saamu 38:21
3
Saamu 38:15
Ṣùgbọ́n sí ọ OLúWA, ìwọ ni mo dúró dè; ìwọ ni, Olúwa Ọlọ́run mi, ẹni tí yóò dáhùn.
Ṣàwárí Saamu 38:15
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò