1
Saamu 45:7
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ìwọ fẹ́ olódodo, ìwọ sì kórìíra ìwà búburú nígbà náà Ọlọ́run, Ọlọ́run rẹ ti yàn ọ́ ṣe olórí àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ, nípa fífi ààmì òróró ayọ̀ kùn ọ́.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 45:7
2
Saamu 45:6
Ọlọ́run láé, àti láéláé ni ìtẹ́ rẹ, ọ̀pá aládé ìjọba rẹ, ọ̀pá aládé òtítọ́ ni.
Ṣàwárí Saamu 45:6
3
Saamu 45:17
Èmí yóò máa rántí orúkọ rẹ̀ ní ìran gbogbo, nígbà náà ni orílẹ̀-èdè yóò yìn ọ́ láé àti láéláé.
Ṣàwárí Saamu 45:17
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò