1
Saamu 53:1
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
BMYO
Aṣiwèrè wí ní ọkàn rẹ̀ pé, “Ọlọ́run kò sí.” Wọ́n bàjẹ́, gbogbo ọ̀nà wọn sì burú; kò sì ṣí ẹnìkan tí ń ṣe rere.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 53:1
2
Saamu 53:2
Ọlọ́run bojú wo ilẹ̀ láti ọ̀run sórí àwọn ọmọ ènìyàn, láti wò bóyá ẹnìkan wà, tí ó ní òye, tí ó sì ń wá Ọlọ́run.
Ṣàwárí Saamu 53:2
3
Saamu 53:3
Gbogbo ènìyàn tí ó ti yí padà, wọ́n ti parapọ̀ di ìbàjẹ́; kò sí ẹnìkan tí ó ń ṣe rere, kò sí ẹnìkan.
Ṣàwárí Saamu 53:3