1
Saamu 79:9
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ràn wá lọ́wọ́, Ọlọ́run Olùgbàlà wa, fún ògo orúkọ rẹ; gbà wá kí o sì dárí ẹ̀ṣẹ̀ wa jì nítorí orúkọ rẹ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 79:9
2
Saamu 79:13
Nígbà náà àwa ènìyàn rẹ, àti àgùntàn pápá rẹ, yóò fi ọpẹ́ fún ọ títí láé; láti ìran dé ìran ni àwa ó fi ìyìn rẹ hàn.
Ṣàwárí Saamu 79:13
3
Saamu 79:8
Má ṣe ka ẹ̀ṣẹ̀ àwọn baba wa sí wa lọ́rùn jẹ́ kí àánú rẹ wá kánkán láti bá wa, nítorí tí a rẹ̀ wá sílẹ̀ gidigidi.
Ṣàwárí Saamu 79:8
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò