1
Saamu 90:12
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Kọ́ wa bí a ti ń kaye ọjọ́ wa dáradára, kí àwa ba à lè fi ọkàn wa sípa ọgbọ́n.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 90:12
2
Saamu 90:17
Jẹ́ kí ẹwà Olúwa Ọlọ́run wa wà lára wa; fi ìdí iṣẹ́ ọwọ́ wa múlẹ̀ lára wa bẹ́ẹ̀ ni, kí ó sì fi ìdí iṣẹ́ ọwọ́ wa múlẹ̀.
Ṣàwárí Saamu 90:17
3
Saamu 90:14
Tẹ́ wa lọ́rùn ní òwúrọ̀ nínú ìṣeun ìfẹ́ rẹ, kí àwa kí ó lè kọrin fún ayọ̀ kí inú wa sì dùn ní gbogbo ọjọ́.
Ṣàwárí Saamu 90:14
4
Saamu 90:2
Kí a tó bí àwọn òkè ńlá àti kí ìwọ tó dá ilẹ̀ àti ayé, láti ayérayé dé ayérayé ìwọ ni Ọlọ́run.
Ṣàwárí Saamu 90:2
5
Saamu 90:1
OLúWA, ìwọ ti jẹ́ ibùgbé wa ní gbogbo ìran dé ìran.
Ṣàwárí Saamu 90:1
6
Saamu 90:4
Nítorí pé ìgbà tí ẹgbẹ̀rún ọdún bá kọjá lójú rẹ, bí àná ni ó rí, bí ìgbà ìṣọ́ kan lóru.
Ṣàwárí Saamu 90:4
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò