1
Orin Solomoni 6:3
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Èmi ni ti olùfẹ́ mi, olùfẹ́ mi sì ni tèmi, Ó ń jẹ láàrín ìtànná lílì.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Orin Solomoni 6:3
2
Orin Solomoni 6:10
Ta ni èyí tí ó tàn jáde bí i ìràwọ̀ òwúrọ̀, tí ó dára bí òṣùpá, tí ó mọ́lẹ̀ bí oòrùn, tí ó ní ẹ̀rù bí i jagunjagun pẹ̀lú ọ̀págun?
Ṣàwárí Orin Solomoni 6:10
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò