ÀWỌN ỌBA KINNI 17:24

ÀWỌN ỌBA KINNI 17:24 YCE

Obinrin náà sọ fún Elija pé, “Mo mọ̀ nisinsinyii pé eniyan Ọlọrun ni ọ́, ati pé òtítọ́ ni ọ̀rọ̀ OLUWA tí ń ti ẹnu rẹ jáde.”