ÀWỌN ỌBA KINNI 18:38

ÀWỌN ỌBA KINNI 18:38 YCE

OLUWA bá sọ iná sílẹ̀, iná náà sì jó ẹbọ náà ati igi, ati òkúta. Ó jó gbogbo ilẹ̀ ibẹ̀, ó sì lá gbogbo omi tí ó wà ninu kòtò.