ÀWỌN ỌBA KINNI 19:6

ÀWỌN ỌBA KINNI 19:6 YCE

Ó wò yíká, ó sì rí ìṣù àkàrà kan, ati ìkòkò omi kan lẹ́bàá ìgbèrí rẹ̀. Ó jẹun, ó mu omi, ó sì tún dùbúlẹ̀.