ÀWỌN ỌBA KINNI 19:7

ÀWỌN ỌBA KINNI 19:7 YCE

Angẹli OLUWA náà pada wa, ó jí i, ó sì wí fún un pé, “Dìde kí o jẹun, kí ìrìn àjò náà má baà pọ̀jù fún ọ.”