ÀWỌN ỌBA KINNI 22:23

ÀWỌN ỌBA KINNI 22:23 YCE

“Nítorí náà, gbọ́ nisinsinyii, OLUWA ni ó jẹ́ kí àwọn wolii wọnyi máa purọ́ fún ọ, nítorí pé ó ti pinnu láti jẹ́ kí ibi bá ọ.”