ÀWỌN ỌBA KINNI 22:7

ÀWỌN ỌBA KINNI 22:7 YCE

Ṣugbọn Jehoṣafati bèèrè pé, “Ṣé kò tún sí wolii OLUWA mìíràn mọ́, tí a lè wádìí lọ́dọ̀ rẹ̀?”