ÀWỌN ỌBA KEJI 2:1

ÀWỌN ỌBA KEJI 2:1 YCE

Nígbà tí àkókò tó fún OLUWA láti fi ààjà gbé Elija lọ sí ọ̀run, Elija ati Eliṣa kúrò ní Giligali.