ÀWỌN ỌBA KEJI 2:8

ÀWỌN ỌBA KEJI 2:8 YCE

Elija bọ́ aṣọ àwọ̀lékè rẹ̀, ó fi lu odò náà, odò sì pín sí meji títí tí Elija ati Eliṣa fi kọjá sí òdìkejì odò lórí ìyàngbẹ ilẹ̀.