ÀWỌN ỌBA KEJI 4:2

ÀWỌN ỌBA KEJI 4:2 YCE

Eliṣa bèèrè pé, “Kí ni o fẹ́ kí n ṣe fún ọ? Sọ ohun tí o ní nílé fún mi.” Obinrin náà dáhùn pé, “N kò ní ohunkohun, àfi ìkòkò òróró kan.”