ÀWỌN ỌBA KEJI 5:10

ÀWỌN ỌBA KEJI 5:10 YCE

Eliṣa rán iranṣẹ kan kí ó sọ fún un pé kí ó lọ wẹ ara rẹ̀ ninu odò Jọdani ní ìgbà meje, yóo sì rí ìwòsàn.