ÀWỌN ỌBA KEJI 6:5

ÀWỌN ỌBA KEJI 6:5 YCE

Bí ọ̀kan ninu wọn ti ń gé igi, lójijì, irin àáké tí ó ń lò yọ bọ́ sinu odò. Ó kígbe pé, “Yéè! Oluwa mi, a yá àáké yìí ni!”