ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 1:9

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 1:9 YCE

Nígbà tí ó ti sọ báyìí tán, bí wọ́n ti ń wò ó, a gbé e sókè, ìkùukùu bò ó, wọn kò sì rí i mọ́.