ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 2:20

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 2:20 YCE

Oòrùn yóo ṣókùnkùn, òṣùpá yóo di ẹ̀jẹ̀, kí ó tó di ọjọ́ ńlá tí ó lókìkí, ọjọ́ Oluwa.