ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 22:14

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 22:14 YCE

Ó bá sọ fún mi pé, Ọlọrun àwọn baba wa ni ó yàn mí tẹ́lẹ̀ pé kí n mọ ìfẹ́ rẹ̀, kí n fojú rí iranṣẹ Olódodo rẹ̀, kí n sì gbọ́ ohùn òun pàápàá