ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 22:16

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 22:16 YCE

Ó wá bèèrè pé, kí ni mo tún ń fẹ́ nisinsinyii? Ó ní kí n dìde, kí n ṣe ìrìbọmi, kí n wẹ ẹ̀ṣẹ̀ mi nù, kí n pe orúkọ Oluwa.