ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 6:7

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 6:7 YCE

Ọ̀rọ̀ Ọlọrun wá ń gbilẹ̀. Iye àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Jesu túbọ̀ ń pọ̀ sí i ní Jerusalẹmu. Pupọ ninu àwọn alufaa ni wọ́n sì di onigbagbọ.