DIUTARONOMI 30:15

DIUTARONOMI 30:15 YCE

“Wò ó, mo gbé ikú ati ìyè kalẹ̀ níwájú yín lónìí, bákan náà ni mo sì gbé ire ati ibi kalẹ̀.