ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 10:10

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 10:10 YCE

Ẹni tí kò bá pọ́n àáké rẹ̀ kí ó mú, yóo lo agbára pupọ bí ó bá fẹ́ lò ó, ṣugbọn ọgbọ́n a máa ranni lọ́wọ́ láti ṣe àṣeyọrí.