ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 11:10

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 11:10 YCE

Gbé ìbànújẹ́ kúrò lọ́kàn rẹ, má sì gba ìrora láàyè lára rẹ, nítorí asán ni ìgbà èwe ati ìgbà ọmọde.