ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 9:17

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 9:17 YCE

Ọ̀rọ̀ jẹ́ẹ́jẹ́ tí ọlọ́gbọ́n bá sọ, ó dára ju igbe aláṣẹ láàrin àwọn òmùgọ̀ lọ.