AISAYA 33:6

AISAYA 33:6 YCE

Yóo mú kí ìdúróṣinṣin wà ní gbogbo àkókò rẹ̀. Yóo fún ọ ní ọpọlọpọ ìgbàlà, ati ọgbọ́n, ati ìmọ̀, ìbẹ̀rù OLUWA ni ìṣúra rẹ̀.