ÀWỌN ADÁJỌ́ 6:17

ÀWỌN ADÁJỌ́ 6:17 YCE

Gideoni tún dáhùn, ó ní, “Bí inú rẹ bá yọ́ sí mi, fi àmì kan hàn mí pé ìwọ OLUWA ni ò ń bá mi sọ̀rọ̀.