JEREMAYA 14:20-21

JEREMAYA 14:20-21 YCE

OLUWA, a mọ ìwà burúkú wa, ati ẹ̀ṣẹ̀ àwọn baba wa, nítorí a ti ṣẹ̀ ọ́. Má ta wá nù nítorí orúkọ rẹ, má sì fi àbùkù kan ìtẹ́ rẹ tí ó lógo. Ranti majẹmu tí o bá wa dá, ranti, má sì ṣe dà á.