ÌWÉ ÒWE 1:28-29
ÌWÉ ÒWE 1:28-29 YCE
Ẹ óo ké pè mí nígbà náà, ṣugbọn n kò ní dáhùn. Ẹ óo wá mi láìsinmi, ṣugbọn ẹ kò ní rí mi. Nítorí pé ẹ kórìíra ìmọ̀, ẹ kò sì bẹ̀rù OLUWA.