Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

ÌWÉ ÒWE 1:7-8

ÌWÉ ÒWE 1:7-8 YCE

Ìbẹ̀rù OLUWA ni ìbẹ̀rẹ̀ ìmọ̀, ṣugbọn àwọn òmùgọ̀ a máa pẹ̀gàn ọgbọ́n ati ẹ̀kọ́. Ìwọ ọmọ mi, gbọ́ ẹ̀kọ́ baba rẹ, má sì kọ ẹ̀kọ́ ìyá rẹ,

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún ÌWÉ ÒWE 1:7-8

ÌWÉ ÒWE 1:7-8 - Ìbẹ̀rù OLUWA ni ìbẹ̀rẹ̀ ìmọ̀, ṣugbọn àwọn òmùgọ̀ a máa pẹ̀gàn ọgbọ́n ati ẹ̀kọ́. Ìwọ ọmọ mi, gbọ́ ẹ̀kọ́ baba rẹ, má sì kọ ẹ̀kọ́ ìyá rẹ,