ORIN DAFIDI 100:2

ORIN DAFIDI 100:2 YCE

Ẹ fi ayọ̀ sin OLUWA. Ẹ wá siwaju rẹ̀ pẹlu orin ayọ̀.