ORIN DAFIDI 107:6

ORIN DAFIDI 107:6 YCE

Nígbà náà ni wọ́n ké pe OLUWA ninu ìpọ́njú wọn, ó sì yọ wọ́n kúrò ninu ìṣẹ́ wọn.