ORIN DAFIDI 19:7

ORIN DAFIDI 19:7 YCE

Òfin OLUWA pé, a máa sọ ọkàn jí; àṣẹ OLUWA dájú, ó ń sọ òpè di ọlọ́gbọ́n.