Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

ORIN DAFIDI 59:16

ORIN DAFIDI 59:16 YCE

Ṣugbọn èmi ó kọrin ìyìn agbára rẹ; n óo kọrin sókè lówùúrọ̀, nípa ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀. Nítorí ìwọ ni o ti jẹ́ odi mi ìwọ sì ni ààbò mi nígbà ìpọ́njú.