ORIN DAFIDI 69:16

ORIN DAFIDI 69:16 YCE

Dá mi lóhùn, OLUWA, nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ dára; fojú rere wò mí, gẹ́gẹ́ bí ọpọlọpọ àánú rẹ.